Morónkọ́lá
Sísọ síta
Ìtumọọ Morónkọ́lá
1. I have found something to add to (my) wealth. 2. I've found something to gather (my) wealth.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-rí-oun-kún-ọlá, mo-rí-oun-kó-ọlá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Irí - see, find
oun - something, someone
kún - add to
ọlá - wealth, nobility
-
mo - I
rí - see, find
oun - something, someone
kó - gather
ọlá - wealth, nobility
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL