Moríre

Sísọ síta



Ìtumọọ Moríre

I've seen goodness.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Moráyọ, Morádé, Morólú



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-rí-ire



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
rí - find, see
ire - goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL