Morádéwún

Sísọ síta



Ìtumọọ Morádéwún

I've found royalty to rejoice in.



Àwọn àlàyé mìíràn

See also: Morádéhún, Morádéyọ̀



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-rí-adé-wún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
rí - see, find
adé - crown
wún - rejoice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Morádéhún