Morájéjẹun

Sísọ síta



Ìtumọọ Morájéjẹun

I've been fed by resourcefulness.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-rí-ajé-jẹun



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
rí - see
ajé - resourcefulness
jẹun - eat