Morẹ́nikéjì
Sísọ síta
Ìtumọọ Morẹ́nikéjì
I've found a companion.
Àwọn àlàyé mìíràn
It's a name given, typically, to the first child after a long wait. It means, I've found someone to keep me company.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-rí-ẹni-kejì
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Irí - see, find
ẹni - person
kéjì - second
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OTHERS