Moríyìíkẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Moríyìíkẹ́
I have found this (child) to care for.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-rí-èyí-kẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Irí - see, find
èyí - this (one)
kẹ́ - to pamper, care for
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL