Mojoyinọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Mojoyinọlá

I enjoy the sweetness of wealth.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-jẹ-oyin-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
jẹ - eat, enjoy
oyin - honey, sweetness
ọlá - wealth


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL
OYO



Irúurú

Mojoyin

Joyin