Mojèrè

Sísọ síta



Ìtumọọ Mojèrè

I gained a reward.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-jèrè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
jèrè - to receive a reward; to gain, profit; to reap


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
EKITI