Mogbádùnọlá

Sísọ síta



Ìtumọọ Mogbádùnọlá

I am enjoying honor.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-gbádùn-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
gbádùn - enjoy
ọlá - wealth, honor


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA