Mofolúkẹ́

Sísọ síta



Ìtumọọ Mofolúkẹ́

I commit him/her to God's care.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-fi-olú-kẹ́



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
fi - with
olú - the prominent one, lord, God
kẹ́ - cherish, care for, pet, pamper


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Folúkẹ́