Mofayọ̀jọláolúwa

Sísọ síta



Ìtumọọ Mofayọ̀jọláolúwa

I am happily enjoying the benefit/privilege/honour of God.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-fi-ayọ̀-jẹ-ọlá-olúwa



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
fi - use
ayọ̀ - joy
jẹ - achieve
ọlá - honour, wealth, nobility, prestige
olúwa - lord, God


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA



Irúurú

Jọláolúwa

Jọlá