Mofaratireolúwami
Sísọ síta
Ìtumọọ Mofaratireolúwami
I'm resting on the goodness of my God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-fi-ara-ti-ire-olú-wa-mi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Ifi - use
ara - body
tì - rest on
ire - goodness
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL