Mofọmọṣará
Sísọ síta
Ìtumọọ Mofọmọṣará
My child is my family.
Àwọn àlàyé mìíràn
See: Ọmọlará
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-fi-ọmọ-ṣe-ará
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Ifi - with
ọmọ - child
ṣe - make, create
ará - kith and kin
Agbègbè
                        Ó pọ̀ ní:
                            
OSUN                            
OYO                    
