Mofọláshadé

Sísọ síta



Ìtumọọ Mofọláshadé

I make royalty from nobility.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-fi-ọlá-ṣe-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
fi - to use, to put
ọlá - wealth, dignity, favour, glory
ṣe - to do, to make
adé - crown, royalty


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Fọlá

Fọláṣadé

Mofọláṣadé

Ṣadé