Modébáyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Modébáyọ̀

I have arrived into joy. I have arrived to meet joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-dé-bá-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
dé - arrive, return
bá - meet
ayọ̀ - joy, happiness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Báyọ̀