Modádéayọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Modádéayọ̀

I wear the crown of joy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-dé-adé-ayọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
dé - sport, put on
adé - crown
ayọ̀ - joy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Dádéayọ̀