Mobádérìn

Sísọ síta



Ìtumọọ Mobádérìn

I walk with the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-bá-adé-rìn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
- together with
adé - crown, royalty
rìn - walk


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OYO



Irúurú

Bádé

Bádérìn

Mobádé