Moṣekọ́lá

Sísọ síta



Ìtumọọ Moṣekọ́lá

I've added to my honour/prestige.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-ṣe-kún-ọlá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
ṣe - work, do
kún - add to
ọlá - honour, prestige, notability


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO