Moṣaléwá

Sísọ síta



Ìtumọọ Moṣaléwá

I have been choosy about which house to get into.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mo-ṣa-ilé-wá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
ṣà - pick, choose, select
ilé - house
wá - come


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Saléwá