Moṣọpẹ́fólúwa
Sísọ síta
Ìtumọọ Moṣọpẹ́fólúwa
I gave thanks to God.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mo-ṣe-ọpẹ́-fún-olúwa
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mo - Iṣe - make, create, do
ọpẹ́ - praises/thanksgiving
fún - for
olúwa - lord, God
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL