Méròyí
Sísọ síta
Ìtumọọ Méròyí
I didn't think of this (one).
Àwọn àlàyé mìíràn
The name expresses surprise either at the gender of the child or at the arrival of the child at all, perhaps due to a pervasive childlessness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mé-rò-èyí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mé - I did notrò - think, imagine
èyí - this
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ONDO