Méròyá

Sísọ síta



Ìtumọọ Méròyá

I couldn't find money to borrow.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mé-rí-owó-yá



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mé - I did not
rí - see, find
owó - money
yá - borrow


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ILESHA