Méṣayétẹ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Méṣayétẹ́
I did not come into the world for mockery.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
mé-ṣe-ayé-tẹ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
mé - I did notṣe - make, create
ayé - life, world
tẹ́ - be disgraced
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL