Mamòrá
Sísọ síta
Ìtumọọ Mamòrá
Don't let money disappear.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
má-mú-owó-rá
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
má - do notmú - make
owó - money
rá - disappear
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
OGUN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Ọlọ́runnímbẹ Mámoorá. Nigerian politician.