Málàólú

Sísọ síta



Ìtumọọ Málàólú

He who brings white emblem to the deity (Ọbàtálá)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mú-àlà-(fún)-olú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mú - pick, bring
àlà - chalk, whiteness (or a white cloth/emblem), purity
fún - for
olú - the prominent one


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL