Málọmọ́
Sísọ síta
Ìtumọọ Málọmọ́
Stop leaving.
Àwọn àlàyé mìíràn
This is a name for perceived àbíkú children, urging them to stay back.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
má-lọ-mọ́
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
má - don'tlọ - go
mọ́ - again
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL