Májìyàgbé

Sísọ síta



Ìtumọọ Májìyàgbé

Do not suffer in vain.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

má-jẹ-ìyà-gbé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

má - do not
jẹ - eat, endure
ìyà - suffering
j'ìyà - suffer
gbé - in vain


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL