Májẹ́kódùnmí
Sísọ síta
Ìtumọọ Májẹ́kódùnmí
Let it not hurt (pain) me.
Àwọn àlàyé mìíràn
A general consensus is that this name is given to a child born after some other misfortune, be it the death of a previous child or any other major catastrophe - as a supplication to the creator to prevent a repeat.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
má-jẹ́-kí-ó-dùn-mí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
má - do notjẹ́ - let
kí - that
ó - it
dùn - pain
mí - me
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IBADAN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Moses Májẹ́kódùnmí
Nigerian gynaecologist and obstetrician.