Màmátóókí
Sísọ síta
Ìtumọọ Màmátóókí
Mother is worthy to be praised.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
màmá-tó-kí
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
màmá - mothertó - is worthy of
kí - greet, praise, salute, adulate
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
EKO
IBADAN
OTHERS
OYO