Mọ́látì

Sísọ síta



Ìtumọọ Mọ́látì

Bring honour to live beside (me).



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mú-ọlá-tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

- to use; to hold (onto); to make, to bring, select
ọlá - wealth, nobility, success, prestige, honour
- with


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Adémọ́látì

Ògúnmọ́látì