Mẹ́bùdé

Sísọ síta



Ìtumọọ Mẹ́bùdé

Come to me with gifts. Meet me with gifts.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mú-ẹ̀bù(n)-dé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mú...de - bring
ẹ̀bùn - gift, goodness


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IJEBU



Irúurú

Mẹ́bùndé