Móyọ̀ádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Móyọ̀ádé

I rejoice over the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

mó-yọ̀-sí-ádé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

mo - I
yọ̀ - rejoice
sí - into
adé - crown


Irúurú

Moyọ̀sádé