Méèlójúẹkún
Sísọ síta
Ìtumọọ Méèlójúẹkún
I have no eyes for tears.
Àwọn àlàyé mìíràn
Perhaps an àbíkú name
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
méè-ní-ojú-ẹkún
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
méè - I do notní - to have
ojú - eyes
ẹkún - crying
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
IJEBU