Májẹ̀ódùnmí

Sísọ síta



Ìtumọọ Májẹ̀ódùnmí

Let me not be in pain.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

má-jẹ́-kí-ó-dùn-mí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

má - do not
jẹ́ - let
- that
dùn - pain
mí - me


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Májẹ́kódùnmí