Lékan

Sísọ síta



Ìtumọọ Lékan

Full name: Ọlálékan/Ọlámilékan - My wealth has been added upon.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(ọlá)-lé-ìkan



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
lé - plus
ìkan - one


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlálékan

Ọlámilékan