Láwóre
Sísọ síta
Ìtumọọ Láwóre
Success attracts kindness.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
(ọ)lá-wọ́-oore
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - success, notabilitywọ́ - drag, attract
oore - goodness, kindness
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL