Látúbọ̀sún

Sísọ síta



Ìtumọọ Látúbọ̀sún

Another way of writing "Ọlátúbọ̀sún".



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(ọ)lá-túbọ̀-sún



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - fortune, wealth, success, nobiility
túbọ̀ - continue to
sún - move (forward)


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọlátúbọ̀sún

Túbọ̀sún