Látọ̀nà

Sísọ síta



Ìtumọọ Látọ̀nà

1. Nobility knows the way. 2. Nobility is right.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-tọ̀-ọnà, ọlá-tọ̀nà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, nobility, wealth
tọ - follow
ọnà - road, lane, way, path
-
ọlá - honour, nobility, wealth
tọ̀nà - do the right thing


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Ọlátọ̀nà