Lásúnmádé

Sísọ síta



Ìtumọọ Lásúnmádé

Wealth moves closer to the crown.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-súnmọ́-adé



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
súnmọ - move close to
adé - crown


Irúurú

Ọlásúnmádé

Lásún