Ládìtí

Sísọ síta



Ìtumọọ Ládìtí

See: Ọládìtí: Honour has become an accomodating canopy.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-di-ìtí



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - honour, wealth, success, nobility, notability
di - become
ìtí - a tree whose top forms a canopy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Ọládìtí

Dìtí