Ládìtàn

Sísọ síta



Ìtumọọ Ládìtàn

The wealth has become generational. (A variant of Ọládìtàn)



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ọlá-dì-ìtàn



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ọlá - wealth
di - becomes
ìtàn - stories/history


Irúurú

Ọládìtàn