Ládọjà
Sísọ síta
Ìtumọọ Ládọjà
See: Ọládọjà: "Honour has become (famous/widely beloved/boisterous) like the marketplace".
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
ọlá-di-ọjà
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
ọlá - honour, wealth, nobility, successdi - becomes
ọjà - market (thus boisterous, happy, famous)
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL
IBADAN
Àwọn Ènìyàn Gbajúọ̀
Rasheed Adéwọ̀lú Ládọjà (the 44th Olúbàdàn of Ìbàdàn)