Lẹshi
Sísọ síta
Ìtumọọ Lẹshi
Arriving in droves or torrents.
Àwọn àlàyé mìíràn
Derived from Ẹ̀gbá phrase referring to a horde or body of people or in describing the wave of attack of the Dahomey in their campaign against Ẹ̀gbá. Usage example: Lẹshi-lẹshi ni wọn wá
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
lẹṣi
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
-Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
ABEOKUTA