Ládéníkà

Sísọ síta



Ìtumọọ Ládéníkà

Shortened form of Aládéníkà, the crowned one is not evil.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

aládé-è-ní-ìkà



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

aládé - royal head, royalty, the owner of a crown
è - does not, did not
- have
ìkà - a cruel/evil thing


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
ONDO



Irúurú

Aládéníkà