Kújímiyọ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Kújímiyọ̀

Death didn't let me rejoice.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ù-jẹ́-mi-yọ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ù - does not
jẹ́ - permit, to exist, to be effective
mi - me
yọ̀ - rejoice


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL