Kújọọ́rẹ̀

Sísọ síta



Ìtumọọ Kújọọ́rẹ̀

Let death leave him be (spare his hands).



Àwọn àlàyé mìíràn

An àbíkú name. See also: Kújọwọ́rẹ̀.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)kú-ju-ọwọ́-rẹ̀



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
jù - throw
ọwọ́ - hands
rẹ̀ - him/hers


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kújọrẹ̀

Kújọwọ́rẹ̀.