Kúdẹlẹ́tì

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúdẹlẹ́tì

Death becomes impossible.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

(i)-kú-di-ẹlẹ́tì



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
di - become
ẹlẹ́tì - impossibility


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
IBADAN



Irúurú

Kúdẹti