Kúṣànú

Sísọ síta



Ìtumọọ Kúṣànú

Death had mercy.



Àwọn àlàyé mìíràn

Though the name is typically written as Kúṣànú, the best phonological representation should be Kúṣàánú.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

ikú-ṣe-àánú



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

ikú - death
ṣe - do
àánú - mercy


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
OTHERS



Irúurú

Kúsànú

Kúsàánú.