Koṣeégbáralé
Sísọ síta
Ìtumọọ Koṣeégbáralé
Cannot be relied upon.
Àwọn àlàyé mìíràn
An àbíkú name.
Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù
kò-ṣeé-gbé-ara-lé
Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ
kò - he/she is notṣeé - worth, capable of
gbé...lé - put on top of
ara - body
gbáralé - rely on
Agbègbè
Ó pọ̀ ní:
GENERAL