Kòníbiírè

Sísọ síta



Ìtumọọ Kòníbiírè

(The child) has nowhere to go.



Àwọn àlàyé mìíràn

This is an àbíkú name.



Ìtúpalẹ̀ Mọ́fímù

kò-ní-ibi-rè



Ìtumọ̀ ẹyọ-ẹyọ

kò - he/she does not
ní - have
ibi - a place
rè - to go


Agbègbè

Ó pọ̀ ní:
GENERAL



Irúurú

Kòníbirè